# AYANMO

- Link: https://sunshinebookseller.com/product/ayanmo/
- Published: 2026-02-28T17:15:03+01:00
- Author: omoba

**ÀYÀNMỌ́** jẹ́ apá kejì **KÉKERÉ ẸKÙN**, ọ̀kan nínú àwọn ìwé àkàgbádùn láti ọwọ́
Afọlábí Ọlábímtán. Nínú ìwé yìí, Àlàbí ti di tíṣà, bákan náà nípa akitiyan ẹ̀kọ́
abẹ́-ilé, ó yege nínú àwọn ìdánwò rẹ̀ láti lọ kọ́ ẹ̀kọ́ ìṣègùn òyìnbó ní òkè-òkun.
Ìrírí Àlàbí pẹ̀lú àwọn tí ń fún ni ní ìwé-ìrìnnà, ìfẹ́ gbígbóná tí Jọkẹ́ gbé kò 
ó lójú ní òkè-òkun, àti ìjìnlẹ̀ èdè tí ó wà nínú ìwé yìí jẹ́ kí a lè sọ nípa rẹ̀
pé, ‘Bẹ́ẹ̀ ni ti Afọlábí Ọlábímtán; ó tún gbé e dé!’

![Stack image](https://sunshinebookseller.com/wp-content/uploads/2026/08/Stack-image.
png "AYANMO 1")

# 10% Off When You Spend ₦500,000

Subscribe to our valued customers' list and claim your coupon to get a 10% discount
the next time you dine in.
