# Owe Ile Baba Wa: Alakoobere Kerin

- Link: https://sunshinebookseller.com/product/owe-ile-baba-wa-alakoobere-kerin-2/
- Published: 2025-12-06T11:42:35+01:00
- Author: omoba

Ilé-iṣé atẹwétà **Francis Heritage Publishers** fẹ́ láti rí i pé àwọn ọmọ ilé-ẹ̀kọ́
aláàkọ́bẹ̀rẹ̀ ní ìmọ̀ nípa òwe Yorùbá nípa kíkà, kí kọ àti lílò òwe lọnà tí ó rọrùn,
tó sì wà ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà Kúríkúlọ́mù fún kíkọ èdè Yorùbá tí Àjọ **Nigerian 
Educational Research and Development Council (NERDC)** fi lélẹ̀. Ìdì níyì tí a fi
gbé àwọn ìwé **Òwe Ilé Baba Wa** jáde fún àǹfààní àwọn ọmọ wa.

Òwe kan sọ pé: **“Ọ̀rịṣà tí a ń sin tí a ń lé ọmọdé sẹ́yìn, ọ̀rịṣà náà kò ní pé
parun”**. A fẹ́ kì àwọn ọmọdé lè pa òwe ké-kèké tó bá gbón àti ìrí rí wọn mu. Bí
àwọn àgbà bá ń pa òwe nínú ìpàdé wọn tàbí láàárín ẹni kan sí èkèjì, ọmọdé 
tó bá ń gbọ́ òwe a ó lè ní òye ohun tí wọ́n ń sọ ní tọ rí pé òwe kì í ṣe a jẹ̀jì
sí òun paápáà.

Ìwé **Òwe Ilé Baba Wa** láti **Alákọ́bẹ̀rẹ̀ Kejì** títì dé **Alákọ́bẹ̀rẹ̀ Kẹfà**
ni a tẹ̀ jáde fún ọmọ ilé-ẹ̀kọ́ aláàkọ́bẹ̀rẹ̀.

![Stack image](https://sunshinebookseller.com/wp-content/uploads/2026/08/Stack-image.
png "Owe Ile Baba Wa: Alakoobere Kerin 1")

# 10% Off When You Spend ₦500,000

Subscribe to our valued customers' list and claim your coupon to get a 10% discount
the next time you dine in.
