Description

ÀYÀNMỌ́ jẹ́ apá kejì KÉKERÉ ẸKÙN, ọ̀kan nínú àwọn ìwé àkàgbádùn láti ọwọ́ Afọlábí Ọlábímtán. Nínú ìwé yìí, Àlàbí ti di tíṣà, bákan náà nípa akitiyan ẹ̀kọ́ abẹ́-ilé, ó yege nínú àwọn ìdánwò rẹ̀ láti lọ kọ́ ẹ̀kọ́ ìṣègùn òyìnbó ní òkè-òkun. Ìrírí Àlàbí pẹ̀lú àwọn tí ń fún ni ní ìwé-ìrìnnà, ìfẹ́ gbígbóná tí Jọkẹ́ gbé kò ó lójú ní òkè-òkun, àti ìjìnlẹ̀ èdè tí ó wà nínú ìwé yìí jẹ́ kí a lè sọ nípa rẹ̀ pé, ‘Bẹ́ẹ̀ ni ti Afọlábí Ọlábímtán; ó tún gbé e dé!’

Additional information

book-author

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “AYANMO”

Your email address will not be published. Required fields are marked *