Description

Iwé yií jé àbájáde işé iwádií ijinl lórí igbàgbó àti ¢sin ibilè
Yorùbá. Ő fi igbàgbó Yorùbá nínú Elédùmarè hàn gégé bí
Qba )run àti Ayé; ó fi àwọn ĝkàn-lé-nírínwó Imolè hàn
gégé bí alákòóso tí Elédumare yàn láti wá mójú tó ayé àti
àwọn ¢dá inú rè, ó sì fi ipò ati isé pàtaki tí a fi rán òkòòkan
àwọn Irúnmolè yii hảnp¢lú.
İwé yií fi ònà tí Yorùbá n gbà sin Qlórun hàn, ó si tún fi
hàn gbangba pé Yorùbá kì í şe Kèferí gégé bí àwọn elésin
öktèrė tiñ pě wộn. Vans
Bí èniyàn bá pe igbá rè ní àákàrà aráyě yóò bá a fi kól¢.
Ohun a ní ló yę ká náání.
VBLISHER
Òkiti èyí ki í şe àkóộta fún Qmỳwé C.L. Adéoyè şùgbón
àrà òtộ leléyií. Eyin nàáę gbà kí ç tộ o wò.

Additional information

book-author

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “Igbagbo Ati Esin Yoruba”

Your email address will not be published. Required fields are marked *