Availability: In Stock

Asa Ati Ise Yoruba

Author: Cl Adeoye
SKU: 401

4,000

Category: Tag:

Description

lwé Aşi àti lşe Yorùbá jé àbiyori iwádit ijinlę àti italèmú ogün awon babanlá wa ti ó tii sorù bí àwọn àgbàlagbà ti á tán ní abérun ayć. lsé ribirbi ni èyi nitori pé àşà abinibi tí a şe iwádif wònyí j¢ àwon ohun ti a le pè ni àwon igi ti àwọn babańilá wa ti lộ, cjúlówó omọ kò si gbọdò tu ủ, àfi kió bomi rin in. Gbogbo ohun pàtaki ti ak¢kòó àti Olikóni nínú kộ Yorübá gbódộ mộ fün idánwò àşekágbá ilé kộ Sékóńii àgbà (SSCE) nipa àwon yà ti àn pè ni Yorùbá ni a kójo sínů iwẻ yii, Bákan náà ni iwé yìí jệ máyàmí fún
akệkòó ilể kộ Olikóni àgbà (NCE) àti akekộo ilé eko Yunifäisiti ti ó yan ekó Yorùba láàyò, ki á tó wả sọ ti ogunlógò àwọn olůfệ aşà àti lşese Yorubá tiyóð fệ mọ àmộdájú nipa irandiran wọn.
Aşe ijinlè ảti ekúnrer¢ alàyé lóri itàn orirun, iwà, işe-owó, işe-onà, áşà ati işèşe dwọn tí à ń pề ni omọ Oòduà. Ojúlówó èdè Yorùbá tí ó bá ilàn. ikotó ode-òní mu ni a fi şe agbékalė àwọn iwádi ộrínkinniwin wònyí. Akóký irů rệ rèé, bộệ “ệyin ni qmọ adię ń tòyá e’ni àwon irúfệ iwe yi ti ó wà lóde siá şe fün un títí di òní. Kí á má purý, atá tó o, iyỳ dùn ún ni or) iwé yil. ldi niyí ti Kábiyèsi, Timi ti hú Edę àná, Qba Adétóyèşe Láoyė, fi pe ‘Láògún ni Dókità Yorùbá’, bí ó tilệ jé pé ‘Dökítà Işègùn’ ni Láogún í e. Kò si eni ti yoò ka iwé yií tí kò ní gbà pé ‘Aràbà ni bàbá, ni a bá lábà ni baba’Qgbộn lẹ fệ kộ ni, abi im) ijinlè? O yá ę fàkàrà túko wò.

Additional information

book-author

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “Asa Ati Ise Yoruba”

Your email address will not be published. Required fields are marked *