Availability: In Stock

O Le Ku

SKU: 415

1,500

4 in stock

Category:

Description

Iwe yii fi ojúlówó Yorúba so nipa awon isoro ti odomokùnrin ti ở i wá aya máa i bá pàdé. Ajani sest jáde ni yunifásiti ni. O fé te Asáke odomobinrin téere awclewa kan ti oun nà sese pari iwè mnéwàá. Asaké fi gbogbo ara wu
Ajàni, sugbón àimowé púpò Asàké ko Ajani lóminú. Lols, omobinrin miiràn fe ba ààrin won jé. Sügbón, babá Asake kékeré kò fệ ki Asàké fé Ajáni. Oyún ti Aşaké ni l’ó pari orò. Sugbộn Aşàké kò fi oyún náà bi omo. Aarin won tún darú. Nigbèhin, ayò Ajàni kún lójó t’ó wá fé Sadé, eni ti kò kàwé tó bée, sugbón ti ó ti ilé rere wá. Ayò náa ko kún dalé nítori pé Ajaní kú ikú mộtò nigbà ti ó n lọ rèé wo
Asàké ti ó fé binú kú ni ilé-iwòsan. Iwé yif dára púpò gégé bii litiréso fün àwon t’ó fe se idánwò bájáde ni ilé-iwé giga àti àwon olukóni, àti fún awon akekoó giga àti t’àwon olukóni, àti awon akékoó Yorübá ni ilé-¢kó giga yunifásiti pèlú; yió si tún jé iwé aládun fún gbogbo àwon tí ó nifeé Yorùbá ni kika. Iyán rèé, obè niyi, iyókù kù sówò eni ebi ń pa?

Additional information

book-author

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “O Le Ku”

Your email address will not be published. Required fields are marked *