Description
Bojúmo bá mo. gbogbo omodé ilé a kóra jo seré. Bojo bả ro, gbogbo ipéerè àdúgbò a kóra jo degbó dègboro. Bi wón bả şeré titi, bó bả dojó alė, kálukú a gbodė baba rè lo sùn. Biwonti ń şeré, ti vwon n sore imülè lojoojümo lojó nlo. Kiwon ó tó fura, ipinyà a dé sààrin won. Eni ti yóò lo Sokótó lo kàwé, eni ti yóo lo Ibàdan lọ kosė. Àni ojó ipinyà báyii, erebe ni. Iwé itàn-àròso tó dá lóri iriri igbà èwe ni Ogún Omọdé. Akàwé isėlè aàrin àwon omodé ni Ojògbón Akinwùmi Isolá fi ogbon itàn gbé kalè so di odidi. Njé omodé şe ở? Njé o somodé ri? Bi o bá tiè somọdé ri tàbi omodé se o ri, mélòó lo ránti ninú ohuntio se tabi tió se o nigbà èwe rė? Bio kò bả ránti, gbiyànjủaiwéyii, kiosi kåá. Odájú pė ketepe ni o ori ara re he.
Reviews
There are no reviews yet.