Description
Nigbà tí RÉRÉ RÚN kókó dé ní 1973, abàmi eré onişe ni. Şügbón lónii, ó ti di gbajú-gbajà. Ninú éré náà, iyà àjęsunkún ni àwọn òşişé ń ję, ni Láwúwo bá kó wọn sòdí láti bá àwọn agbanisíşć forí gbári, tí reré fi rún. Àtúnkọ eré náà niyí, níbi tí åwon òşişé ti wáá jà raburabu láti bộ nínú iyà. Şùgbộn àbá ni ikán ń dá, ikán ò le mu òkúta. Bębękú¢bè, ibè náà ló ń b). Rérệ tún rún náà ni, jégéjégé ló rún.
Reviews
There are no reviews yet.