Description
ljinle Ohin Enu Ifá Apá Kin-in-ní ní akókộ ninú owó iwé tí 6 tú
perepére lóri ese 1fá. iwé yií sälayé kikún lórí Ifá, kí ó ó se ảkosile
àwon ese méjoméjo nínú àwon se Ifa ti ó wà ninú okookan àwon ojú
odù méreğrindínlógún, bère láti ori Eji ogbè títí dé ori Ofun méji.
Iwé yii tún gbiyànjú sålayé àwon oro tí ó ta kókó nínú àwon esę Ifá
wònyí tí 6 se é se kí ó je idäämú fún olükó, akékoó àti àwon onkäwé
wa gbogbo.
Pėlá iranlówó iwé yií, isöro ese Ifá gége bi okan ninú àwon ewi
alohün Yorùbá ti di irorùn.
Ojò ni iwé yi, bó se dára fún omodé bée ló wúlo fün àgbà.
Afin tí kö nilò à-ún-júwe lójà ni Ojògbộn “Wándé Abimbölá inú
onímo ní gbogbo àgbáyć. O ti gbé opòlopo iwé ati isé iwádii papåá
lóri ifá jáde.
Reviews
There are no reviews yet.