Description
jinlė Ohún Enu lfä Apá Keji ni ekeji nínú öwo iwé ti ó tú perepệrė
lóri ese Ifá. O jé itèsíwájú fün Apá Kin-ín-ní. A se åkosilè àwon ese
méjoméjo nínú awon esę Ifá tí ó wả ninú okookan àwon ojú odù
mérèerindinlógún, beẻ láti orí Eji ogbè titi dé ori Ofün méji.
İwé yii tún gbiyànjú sàläyé àwon orò tí ó ta kókó nínú áwon gsę Ifã
wonyí ti ó se é se kí ó jé idàämú fún olükó, akékoó åti äwon önkàwé
wa gbogbo.
Pèlú irånlówó iwé yií, isöro ese Ifä gégé bi okan ninú àwon ewi
alohün Yorübáti di irğrùn.
Öjò ni iwé yi, bó se dára fün omodé bée ló wúlo fün ägbà.
Afin tí kò nílo å-ún-júwe lójà ni Ôjögbộn “Wándé Abimbólá ninú
nimo ní gbogbo àgbáyé. Ó ti gbé opölopò iwé àti isệ iwádii papåá
lórí Ifá jáde.
Reviews
There are no reviews yet.