Description
Iwẻ yià je à kójopò ese Ifá ti a mú láti inú à won Ojú Odù (Olojà ) Mérèerindinlógún. A mú ese Ifá méjo-méjo láti inů Odù kookan bèrè láti inú Eji Ogbè tÃti tà ó fi kan Ofün (Orà ngún) Méji. lyà tò ti ở wà nÃnú iwé yii à ti à won iwé Ifá ati ewi à dáyébá miirà n ni pé a se à là yé ese IfÃ¥ kòòkan tiÅ„ bẹ ninú iwé yii léseese. A se èyà nitori pé ati ÅŸe à kiyèsi wi pé à won ese Ifá wonyà kii yé à won akékoo à ti olùkó náà dáadáa nigbà tà won bá Å„ kà won. Edè à tayé báyé ni èdè Orúnmilà . Nitorà náa kò ya ‘ni lénu wipé èdè lIfá ki à tètè yé ogbèri. ldi niyà ti a fi se à là yé sókisókà lóri esÄ™ koökan. Fún eni ti ó bá ni òye ti ó si nà ife si ese Ifä, a lérò pé à là yé wònyi ó jèe ilà nà pà täki nigbà ti ó baÅ„ ka iwé yii finÃfini. Ni ibère iwé yii, a se à là yé nipa ohun ti Ifa je gége bi orisà à ti ewi à dáyébá Yorùbá. A lérò wi pé à là yé yii náà ó ran à wỌn ònkà wé wa lówó láti mo ipò ti Ifá kó ninú ogbá»™n, imò à ti irÃri omo Yorùbá.







Reviews
There are no reviews yet.